Kíyèsí i, bí i kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ìgbẹ́ nínú ijùni àwọn talákà ijáde lọ sí iṣẹ́wọn; Wọ́n a tètè dìde láti wáohun ọdẹ; ijù pèsè oúnjẹ fúnwọn àti fún àwọn ọmọ wọn