Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 21:30-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Ènìyàn búburú ní a fi pamọ́ fúnọjọ́ ìparun? A ó sì mú wọnjáde ní ọjọ́ ríru ìbínú.

31. Ta ni yóò sọ ipa ọ̀nà rẹ̀ kò ó níojú, ta ni yóò sì san án padà fún un ní èyí tí ó ti ṣe?

32. Síbẹ̀ a ó sì sin ín ní ọ̀nà ipò òkú, a ósì máa ṣọ́ ibojì òkú.

33. Ògúlùtù àfonífojì yóò dùn mọ́ ọn.Gbogbo ènìyàn yóò sì máa tọ̀ ọ́lẹ́yìn, bí ènìyàn àìníye ti lọ ṣíwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin Jóòbù 21