Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 21:18-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Wọ́n dàbí àkékù oko níwájúafẹ́fẹ́, àti bí ìyàngbò, tí ẹfúùfù ńlá fẹ́ lọ.

19. Ẹ̀yin wí pé, ‘Ọlọ́run to iya ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀jọ fún àwọn ọmọ rẹ̀.’ Jẹ́ kí ó san án fún un, yóò sì mọ̀ ọ́n.

20. Ojú rẹ̀ yóò rí ìparun ara rẹ̀, yóòsì máa mu nínú ríru ìbínú Olódùmarè.

21. Nítorí pé àlàáfíà kí ni ó ní nínú ilérẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀, nígbà tí a bá ké iye oṣù rẹ̀ kúrò ní agbede-méjì?

Ka pipe ipin Jóòbù 21