Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ó dá a lóhùn pé, “Ìwọ sọ̀rọ̀ bí ọ̀kan lára àwọn obìnrin aláìmọ́ye ti í sọ̀rọ̀; há bà! Àwa yóò ha gba ire lọ́wọ́ Ọlọ́run, kí a má sì gba ibi?”Nínú gbogbo èyí, Jóòbù kò fi ètè rẹ̀ ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Jóòbù 2

Wo Jóòbù 2:10 ni o tọ