Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 12:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn a máa fi ọwọ́ ta ilẹ̀ nínú òkùnkùn níbi tí kò sí ìmọ́lẹ̀,Òun a sì máa mú wọn tàsé ìrìn bí ọ̀mùtí.

Ka pipe ipin Jóòbù 12

Wo Jóòbù 12:25 ni o tọ