Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jónà 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónà sì jáde kúrò ní ìlú náà, ó sì jókòó níhà ìlà-oòrùn ìlú náà. Ó sì pa àgọ́ kan níbẹ̀ fún ara rẹ̀, ó sì jókòó ni ibòòji ní abẹ́ rẹ̀ títí yóò fi rí ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí ìlú náà.

Ka pipe ipin Jónà 4

Wo Jónà 4:5 ni o tọ