Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò si tà àwọn ọmọkùnrin yín àti àwọn ọmọbìnrin yín sí ọwọ́ àwọn ọmọ Júdà, wọ́n yóò sì tà wọ́n fún àwọn ara Ṣábíà, fún orílẹ̀ èdè kan tí ó jìnnà réré.” Nítorí Olúwa ní o ti sọ ọ.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 3

Wo Jóẹ́lì 3:8 ni o tọ