Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò sì mú ọdún wọ̀nyí ti eṣú jẹ run padà fún un yín.Èyí tí eṣú agénijẹ àti eṣú jewéjewéọwọ́ eṣú agénijẹ àti kòkòro ajẹnirun mìíràn ti fi jẹàwọn ogun ńlá mí tí mo rán sí àárin yín.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:25 ni o tọ