Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́, Olúwa yóò dá wọn lóhùn:“Yóò sì wí fun àwọn ènìyàn rẹ̀ pé,Wò ó èmi yóò rán ọkà, àti ọtí wáìnì tuntun,àti òróró síi yín, a ó sì fi wọn tẹ́ yín lọ́rùn:èmi kì yóò si fí yín ṣe ẹ̀gan mọ́ láàrin àwọn aláìkọlà.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:19 ni o tọ