Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 9:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí sì ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Àwọn ọmọ ogun wí:“Ṣáà wò ó nísisìnyìí! Ké sí obìnrin ọlọ́fà nì kí ó wá;sì ránsẹ́ pe àwọn tí ó mòye nínú wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:17 ni o tọ