Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sì tú wọn ká láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, nínú èyí tí àwọn tàbí àwọn baba wọn kò mọ̀. Èmi yóò sì lépa wọn pẹ̀lú idà títí èmi yóò fi pa wọ́n run.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:16 ni o tọ