Ojú yóò ti àwọn ọlọ́gbọ́n, a ó dàwọ́n láàmú, wọn yóò sì kó sí ìgbèkùn.Nítorí wọ́n ti kọ ọ̀rọ̀ Olúwa. Irú ọgbọ́nwo ló kù tí wọ́n ní?