Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, èmi yóò fi ìyàwó wọn fúnàwọn ọkùnrin mìíràn àti ilẹ̀ wọnfún àwọn ẹlòmíràn láti èyí tó kéréjù dé èyí tó dàgbà jù, gbogbo wọnni èrè àjẹjù ń já lẹ́nu; àwọn wòlíìàti àwọn àlùfáà pẹ̀lú ń hùwà ẹ̀tàn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 8

Wo Jeremáyà 8:10 ni o tọ