Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 7:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ti kọ́ àwọn ibi gíga ti Tófẹ́tì ní àfonífojì Beni Hínómí láti sun àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin wọn nínú iná èyí tí èmi kò paláṣẹ tí kò sì wá sí ọkàn mi.

Ka pipe ipin Jeremáyà 7

Wo Jeremáyà 7:31 ni o tọ