Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 7:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Àwọn ènìyàn Júdà ti ṣe búburú lójú mi, ni Olúwa wí. Wọ́n ti to àwọn ère ìríra wọn jọ sí ilé tí a fi orúkọ mi pè wọ́n sì ti sọ ọ́ di àìmọ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 7

Wo Jeremáyà 7:30 ni o tọ