Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 7:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n wọn kò gbọ́, wọn kò sì fetí sílẹ̀ dípò èyí wọ́n ń tẹ̀ sí ọ̀nà agídí ọkàn wọn. Dípò kí wọn tẹ̀ṣíwájú wọ́n ń rẹ̀yìn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 7

Wo Jeremáyà 7:24 ni o tọ