Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 7:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo pàṣẹ fún wọn báyìí pé: Gbọ́ tèmi, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín ẹ̀yin yóò sì jẹ́ ènìyàn mi. Má a rìn ní ojú ọ̀nà tí mo paláṣẹ fún yín, kí ó lè dára fún yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 7

Wo Jeremáyà 7:23 ni o tọ