Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Dúró ní ẹnu ọ̀nà ilé Olúwa kí o sì kéde ọ̀rọ̀ yí:“ ‘Ẹgbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa gbogbo ẹ̀yin ará Júdà tí ń gba ọ̀nà yí wọlé láti wá sin Olúwa.

Ka pipe ipin Jeremáyà 7

Wo Jeremáyà 7:2 ni o tọ