Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Ẹ dúró sí ìkòríta, kí ẹ sì wò,ẹ bere fún ipa ìgbàanì, ẹ bèèrèọ̀nà dáradára nì, kí ẹ sì wọinú rẹ, ẹ̀yin yóò sì rí ìsinmifún ọkàn yín.Ṣùgbọ́n ẹ̀yin wí pé, ‘Àwa kì yóò rin nínú rẹ.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 6

Wo Jeremáyà 6:16 ni o tọ