Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú há a tì wọ́n nítorí ìwàìríra wọn bí? Rárá, wọn kòní ìtìjú mọ́, wọn kò tilẹ̀ ní ooru ìtìjúNítorí náà, wọn ó ṣubú láàrinàwọn tó ṣubú, a ó sì ké wọnlulẹ̀ nígbà tí mo bá fìyà jẹ”wọ́n ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 6

Wo Jeremáyà 6:15 ni o tọ