Èmi yóò fi ìyà jẹ Bélì tiBábílónì àti pé èmi yóòjẹ́ kí ó pọ gbogbo àwọn ohun tí ó gbé mì.Orílẹ̀ èdè kò ní i jẹ́ ìṣàn fún-un mọ́.Odi Bábílónì yóò sì wó.