Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, báyìí ni Olúwa wí:“Wò ó, èmi yóò tì ọ́ lẹ́yìn lóríohun tí o fẹ́ ṣe. Èmi ó sì gbẹ̀san,èmi yóò mú kí omi òkun rẹ̀ àti orísun omi rẹ̀ gbẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 51

Wo Jeremáyà 51:36 ni o tọ