Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nebukadinésárì Ọba Bábílónì tó jẹ wá run,ó ti mú kí ìdààmú bá wa,ó ti sọ wá di àgbá òfìfo.Gẹ́gẹ́ bí ejò, ó ti gbé wa mì.Ó fi oúnjẹ àdídùn wa kún inú rẹ̀,lẹ́yìn náà ni “Ó pọ̀ wá jáde.

Ka pipe ipin Jeremáyà 51

Wo Jeremáyà 51:34 ni o tọ