Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbé àṣíá sókè ní ilẹ̀ náà, fọnipe láàrin àwọn orílẹ̀ èdè!Pèṣè àwọn orílẹ̀ èdè sílẹ̀ láti bá jagun,pe àwọn ìjọba yìí láti doju kọ ọ́,Árárátì, Mínínì àti Ásíkẹ́nì.Yan olùdarí ogun láti kọlù ú,rán àwọn ẹṣin síi bí ọ̀pọ̀ eṣú.

Ka pipe ipin Jeremáyà 51

Wo Jeremáyà 51:27 ni o tọ