Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ohùn ti Olúwa nìyìí:“wò ó èmi yóò ru ẹ̀míapanirun kan sókè síBábílónì àwọn ènìyàn Lébíkámáì

2. Èmi yóò rán àwọn àjèjì ènìyàn síBábílónì láti ba ilẹ̀ jẹ́,wọn yóò ṣe àtakò rẹ̀ ní gbogboọ̀nà ní ọjọ́ ìparun rẹ̀.

3. Má ṣe jẹ́ kí tafàtafà yọ ọfà rẹ̀jáde tàbí kí o di ìhámọ́ra rẹ̀;má ṣe dá àwọn ọdọ́mọkùnrinsí, pátapáta ni kí o pa àwọn ọmọ ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 51