Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 50:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wò ó! Ọ̀wọ́ ọmọ ogun láti ìhà àríwá;orílẹ̀ èdè ńlá àti àwọn Ọba pípọ̀ ni à ńgbé dìde láti òpin ilẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Jeremáyà 50

Wo Jeremáyà 50:41 ni o tọ