Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 50:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Pe ọ̀pọ̀lopọ̀ ènìyàn, àní gbogbo tafàtafà, sórí Bábílónì,ẹ doti iyikakiri, ma jẹ́ ki ẹnikẹ́ni sálà.Sán fún un gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi gbógbó èyí ti o ti ṣé,ẹ ṣe bẹ́ẹ̀ síi, nítorí tí ó ti gberagasí Olúwa, sí Ẹni-MÍMỌ̀ Ísirẹ́lì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 50

Wo Jeremáyà 50:29 ni o tọ