Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ni ṣe tí èmi ó ṣe dáríjì ọ́?Àwọn ọmọ rẹ ti kọ̀ mí sílẹ̀àti pé wọ́n ti fi ọlọ́run tí kì í ṣe Ọlọ́run búra.Mo pèṣè fún gbogbo àìní wọn,síbẹ̀ wọ́n tún ń ṣe panṣágàwọ́n sì kórajọ sí ilé àwọn alágbérè.

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:7 ni o tọ