Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 5:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké,àwọn àlùfáà sì ń ṣe àkóso pẹ̀lú àṣẹ ara wọn,àwọn ènìyàn mi sì nífẹ̀ẹ́ sí èyí,kí ni ẹ̀yin yóò ṣe ní òpin?

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:31 ni o tọ