Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 5:29-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Èmi kì yóò ha fi ìyà jẹ wọ́n fún èyí bí?”ni Olúwa wí.“Èmi kì yóò wá gbẹ̀san ara milára orílẹ̀ èdè bí èyí bí?

30. “Nǹkan ìbànújẹ́ àti ohun ìtarati ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ náà.

31. Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké,àwọn àlùfáà sì ń ṣe àkóso pẹ̀lú àṣẹ ara wọn,àwọn ènìyàn mi sì nífẹ̀ẹ́ sí èyí,kí ni ẹ̀yin yóò ṣe ní òpin?

Ka pipe ipin Jeremáyà 5