Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 49:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòtọ́, àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin rẹyóò ṣubú lójú pópó, gbogboàwọn ọmọ ogun rẹ yóò paẹnu mọ́ ní ọjọ́ náà,”ní Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 49

Wo Jeremáyà 49:26 ni o tọ