Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 44:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: Wo ibi tí mo mú bá Jérúsálẹ́mù àti gbogbo ìlú Júdà. Lónìí, wọ́n wà ní ìyapa àti ìparun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:2 ni o tọ