Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 44:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ Jeremáyà wá nípa àwọn Júù tí ń gbé ní ìsàlẹ̀ Éjíbítì ní Mígídò, Táfánásì àti Mémífísì àti ní apá òkè Íjíbìtì:

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:1 ni o tọ