Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 42:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀yin bá gbé ní ilẹ̀ yìí, èmi yóò gbé e yín ró, n kò sí ní fà yín lulẹ̀, èmi yóò gbìn yín, n kì yóò fà yín tu nítorí wí pé èmi yí ọkan padà ní ti ibi tí mo ti ṣe sí i yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 42

Wo Jeremáyà 42:10 ni o tọ