Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n tí o kò bá jọ̀wọ́ ara rẹ fún àwọn ìjòyè Ọba Bábílónì, a ó fa ìlú yìí lé ọwọ́ àwọn Bábílónì. Wọn yóò sì fi ina sun-un, ìwọ gan-an kò ní le sá mọ́ wọn lọ́wọ́.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:18 ni o tọ