Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jeremáyà sọ fún Sedekáyà pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run alágbára, Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: ‘Àyàfi bí o bá jọ̀wọ́ ara rẹ fún àwọn olóyè Ọba Bábílónì, a ó dá ẹ̀mí rẹ sí àti pé ìlú yìí kò ní di jíjó níná; ìwọ àti ilé rẹ yóò sì wà láàyè.

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:17 ni o tọ