Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 37:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kódà tó bá ṣe pé wọn yóò ṣẹ́gun àwọn ọmọ ogun Bábílónì tí ń gbógun tì yín àti àwọn tí ìjàǹbá ṣe, tí wọ́n ti fi sílẹ̀ ní ibùdó wọn; wọn yóò jáde láti jó ìlú náà kanlẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 37

Wo Jeremáyà 37:10 ni o tọ