Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 36:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì wí fún Jéhóíákímù Ọba Júdà pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí: Ìwọ ti fi ìwé kíká náà jóná, o sì wí pé, “Èése tí ìwọ fi kọ̀wé sínú rẹ̀, pé lòótọ́ ni Ọba Bábílónì yóò wá, yóò sì pa ilẹ̀ run, àti ènìyàn, àti ẹranko kúrò nínú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 36

Wo Jeremáyà 36:29 ni o tọ