Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 36:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn tí wọ́n fi ìwé kíkà náà pamọ́ sí iyàrá Elisámà akọ̀wé, wọ́n sì wọlé tọ Ọba lọ nínú àgbàlá, wọ́n sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ náà ní etí Ọba.

Ka pipe ipin Jeremáyà 36

Wo Jeremáyà 36:20 ni o tọ