Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 35:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi rán gbogbo àwọn ìránṣẹ́ àti àwọn wòlíì mí sí yín pẹ̀lú wí pé, “Ẹ yípadà nísisiyìí kúrò ní ọ̀nà búburú yín, kí ẹ sì tún ìṣe yín ṣe sí rere. Kí ẹ ma sì ṣe bọ òrìṣà tàbí sìn wọ́n; ẹ̀yin ó sì máa gbé ní ilẹ̀ náà tí mo fi fún un yín àti fún àwọn baba ńlá yín.” Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò fetí sími.

Ka pipe ipin Jeremáyà 35

Wo Jeremáyà 35:15 ni o tọ