Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 35:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Ọ̀rọ̀ Jónádábù ọmọ Rékábù tí ó pa láṣẹ fún àwọn ọmọ rẹ̀ pé wọn kò gbọdọ̀ mu ọtí wáìnì, ni a mú sẹ, wọn kò sì mu ọtí wáìnì títí di òní yìí, nítorí tí wọ́n gba òfin baba wọn. Èmi sì ti ń sọ̀rọ̀ fún un yín, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò fetí sími.

Ka pipe ipin Jeremáyà 35

Wo Jeremáyà 35:14 ni o tọ