Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọjọ́ tí wọ́n ti kọ́ ọ, títí di àkókò yìí ni ìlú yìí ti jẹ́ ohun ìbínú àti ìyọnu fún mi tó bẹ́ẹ̀ tí èmi yóò fà á tu kúrò níwájú mi.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:31 ni o tọ