Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì àti Júdà kò ṣe ohun kankan bí kò ṣe ibi lójúmi láti ìgbà èwe wọn. Nítorí àwọn ọmọ Isreli ti fi kìkì iṣẹ́ ọwọ́ wọ́n mú mi bínú ni Olúwa wí

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:30 ni o tọ