Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O fi ìfẹ́ hàn sí ẹgbẹ̀gbẹ̀rún àwọn ènìyàn, ṣùgbọ́n o gbé ìyà ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba lé àwọn ọmọ lẹ́yìn wọn. Ọlọ́rùn títóbi àti alágbára, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:18 ni o tọ