Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Áà! Olúwa àwọn ọmọ-ogun gbogbo, ìwọ tí o dá ọ̀run àti ayé pẹ̀lú títóbi agbára rẹ àti gbogbo ọ̀rọ̀ apá rẹ. Kò sí ohun tí ó ṣòro fún ọ láti ṣe.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:17 ni o tọ