Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 31:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò ní sí pé ọkùnrin kan ń kọ́ àwọn ará ilé rẹ̀tàbí ọkùnrin ń kọ́ arákùnrin rẹ̀ pé, ‘Ẹ mọ Olúwa,’nítorí gbogbo wọn ni yóò mọ̀ míláti ẹni kékeré wọn títídé ẹni ńlá,”ni Olúwa wí.“Nítorí èmi ó dárí àìṣedédé wọn jì,èmi kò sì ní rántí ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 31

Wo Jeremáyà 31:34 ni o tọ