Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 31:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbé àmì ojú ọ̀nà dìde,ṣe atọ́nà àmì,kíyèsí pópónà rélùwéèojú ọ̀nà tí ó ń gbà.Yípadà ìwọ wúndíá Ísírẹ́lì,padà sí àwọn ìlú rẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 31

Wo Jeremáyà 31:21 ni o tọ