Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 31:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éfúráímù kì í ha í ṣe ọmọkùnrin mi dáradáratí inú mi dùn sí bí?Bí èmi ti ń sọ̀rọ̀ sí i tó,síbẹ̀, èmi rántí rẹ̀.Nítorí náà, ọkàn mi ṣe ohun kan fún un,èmi káàánú gidigidi fún un,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 31

Wo Jeremáyà 31:20 ni o tọ