Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 31:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn wúndíá yóò jó, wọn ó sì kún fún ayọ̀,bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ọkùnrin àti obìnrin.Èmi yóò sọ ọ̀fọ̀ wọn di ayọ̀,dípò ìkorò èmi yóò tù wọ́n nínú.Èmi ó sì fún wọn ní ayọ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 31

Wo Jeremáyà 31:13 ni o tọ