Ọmọ ọmọ wọn yóò wà bí i ti ìgbàanìníwájú mi ni wọn yóò sì tẹ àwùjọ wọn dúró sí.Gbogbo ẹni tó bá ni wọ́n lára,ni èmi yóò fìyà jẹ.